Zestful musical team, songwriter and contemporary worship leader Tabernacle Mass Choir arrives again with an amazing and spiritual sound of worship titled Aigbagbo Bila.
Here is another beautiful opportunity to serve the Lord this newly released melody. Get it now below and please share with other christian music lovers. God bless you as you spread his message.
LYRICS: Tabernacle Mass Choir – Aigbagbo Bila
Orin 330: AIGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa
Ẹsẹ 1
AIGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa
On o si dide fun igbala mi;
Ki nsa ma gbadura, On o se ‘ranwo;
‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Ẹsẹ 2
B’ona mi ba nsu, On lo’nsa nto mi,
Ki nsa gboran sa, On o si pese;
B’ iranlowo eda gbogbo ba saki,
Oro t’ enu Re so y’o bori dandan.
Ẹsẹ 3
Ife t’ o nfi han, ko je ki nro pe,
Y’o fi mi sile ninu wahala;
Iranwo ti mo si nri lojojumo,
O nki mi l’ aiya pe emi o la ja.
Ẹsẹ 4
Emi o se kun tori iponju,
Tabi irora? O ti so tele!
Mo m’ oro Re p’ awon ajogun ‘gbala,
Nwon ko le sai koja larin wahala.
Ẹsẹ 5
Eda ko le so kikoro ago
T’ Olugbala mu k’ elese le ye;
Aiye Re tile buru ju t’emi lo,
Jesu ha le jiya, k’ emi si ma sa.
Ẹsẹ 6
Nje b’ ohun gbogbo ti nsise ire,
Adun n’ ikoro, onje li ogun;
B’ oni tile koro, sa ko nip e mo,
Gbana orin ‘segun yio ti dun to!